. Mo tun ki yin , E ku
ojumo ooo , Ojumo ayo lo ma mon gbogbo wa loni o (Amin Ase). Huuuummmm ,
e ma binu pe mo mi kanle lekan si I . Oro awon omobinrin ile iwe Chibok
ti awon iko gbemi gbemi Boko Haram ko ni igbekun lati bi osu die seyin
lo ma n ko mi lominu , die lara foto awon omo naa niyi o , mo wa n fi
asiko yi ati ola inu osu ti a wa yi be eyin omo leyin Ifa, Kristi ati
Musulumi lati bawa gbe oun adura soke ki awon omo yi pada wale layo ati
alafia ............
Femi Ojewale
No comments:
Post a Comment