Wednesday, April 16, 2014
ORO BURUKU ATI ERIN: Imaobong Udoh ni arabinrin yi n je
Imaobong Udoh ni arabinrin yi n je , o ti wa ni ago awon olopa ni ipinle Akwan lbom lori esun pe o ta omo bibi inu ara re ni#260,000 omo ojo meta fun Regina ati Mfon James ti won je tokotaya , Bakan naa ni owo awonolopa ti te arabinrin Comfort Herry eni ti o gbebi fun lmaobong ati ogbeniEmmanuel Okon ti o je alarina bi omo ojo meta naa se di rira. Saaju ni baba omo yi ogbeni Udoh ti fi ejo sun ni ago olopa pe omo oun ti sonu ki owo to wa te awon asebi naa. Ninu oro tire , oko obinrin ti won fi esun ogbeni James ni oun ko gbe ile , iyawo oun kan pe oun pe oun loyun ni ati pe ise oun ko fun oun laaye ati pe awon onisegun ti so fun oun lati maa daamu re.
Oro ree oooooooo
ORO RE E OOOOO!!! Eyin odomobinrin wa . Annabella Zwyndlla niyi
Ninu oro re o ni bi ko tile rorun , sugbon oun ti pinu pe oko ti oun ba fe ni yo ja ibale oun. o ni bi o tile je pe ko si iru fiimu ti oun ko le sibe ko so oun di asewo rara.
Tabi e ko wa ri pe awon omo gidi si tun wa ninu ise tiata bi ti Olootu ORO TO N LO alaya ma l'ale. Huuuuuummmmmmmm.
Tuesday, April 15, 2014
Oro Awon Boko Haram Yi Toju Su Wa O !!!!
Femi Ojewale
WAHALA WA O: Orile ede ti egberun lona edegbeta odo 500,000
WAHALA WA O !!!!! Kin ni e ro pe yoo ma sele ni Orile ede ti egberun lona edegbeta odo 500,000 ti kowe mo n wase si ile ise asobode ti won ti fe gba egberun merin 4,000 eniyan pere , eyi ti o fa iku opolopo awon odo laipe yi. Hummn, laipe yi ni owo te awon odo yi ni adugbo Leki ni ilu Eko nibi ti won ti n sise yahoo , awon odo ti won ko ti i pari eko yunifasiti won. Nibo la n lo l'orile ede yi nibi ti oro awa odo ko ti kan awon asiwaju wa. O ma se oooooooo !!!!
IBUKUN YANTURU - Opolopo ni ona ti ibikun
Monday, April 14, 2014
Yoruba religion - South-West Nigeria springs
When we talk about Yoruba or Yoruba religion, the African race particularly the Yoruba people of South-West Nigeria springs to mind. Nope! There are Yoruba aboriginals in Togo and Benin Republic.
There are native Caribbeans and South Americans who have adopted Yoruba culture and most interestingly, they passionately follow our own ancestral faith “The Yoruba Religion” called Santeria (Lucumi) in the Americas.
Photo: Babalawo Fabunmi performing the Ifa divination on some Ifa devotees.
Subscribe to:
Posts (Atom)