Showing posts with label Ìbéèrè mi nìní. Show all posts
Showing posts with label Ìbéèrè mi nìní. Show all posts

Saturday, April 26, 2014

Ekú déédé ìwòyí o! - Ìbéèrè mi nì

Ekú déédé ìwòyí o!
Èyin èèyàn mi lórí ètò yí, ejòwó ebámi dásí òrò yí, bí àwon baba wa nílè yorùbá báfé júbà won a máa so báyìí pé;
ÌBÀ AKÓDÁ, ÌBÀ ASÈDÁ, ÌBÀ ÀTIWÁSÁYÉ. Ìbéèrè mi nìní; tani akódá?
Tani Asèdá?
Kíni àtiwásáyé?

ST