.                             Mo tun ki yin , E ku 
ojumo ooo , Ojumo ayo lo ma mon gbogbo wa loni o (Amin Ase).  Huuuummmm ,
 e ma binu pe mo mi kanle lekan si I . Oro awon omobinrin ile iwe Chibok
 ti awon iko gbemi gbemi Boko Haram ko ni igbekun lati bi osu die seyin 
lo ma n ko mi lominu , die lara foto awon omo naa niyi o , mo wa n fi 
asiko yi ati ola inu osu ti a wa yi be eyin omo leyin Ifa, Kristi ati 
Musulumi lati bawa gbe oun adura soke ki awon omo yi pada wale layo ati 
alafia ............
Femi Ojewale
 
No comments:
Post a Comment