Ọmọ Oódua - Art & Culture
Yoruba Art And Culture
Pages
(Move to ...)
News
About Us
Entertainment
Naija Gist
Art
Disclaimer
Privacy Policy
▼
Friday, September 26, 2014
Ko Se Duro Wo !
›
Ko se duro wo, bo se nlọ la ntẹle…ohun awọn ọmọ igboro ni Ko kuku si irọ nbẹ, Yoruba gan sọ wipe ‘atatọ ni’, bo ba se nta, ni ko ma tẹle...
Tuesday, September 23, 2014
Nje O Boju Mu Kii Abiyamon Ma Fun Omo ... ??
›
Kii Abiyamon Ma Fun Omo Re Ni oyan N'Ibi Ti Opolopo Eniyan Wa. Beni Tabi Beko???
Tuesday, September 16, 2014
LO BA TAN: Kin lo le mu ki eniyan ri iku n'ile ki o si maa f'owo to o ni imu?
›
Kin lo le mu ki eniyan ri iku n'ile ki o si maa f'owo to o ni imu , bee gege ni oro okunrin ti e n wo yi ri ni adugbo Iju ni ilu...
Saturday, September 13, 2014
Ijamba Se IKo Boko Haram
›
Ni asale ojo isegun ti o koja ni awon odo iko oju lalakan fi s'ori ni ijoba ibile Michika ati Madagali ni ipinle Adamawa so fun awon...
Thursday, September 11, 2014
ARANBARA! Mewa n sele l'oke eepe ,
›
Okunrin kan lo sa deedee wo eka ile ifowopamo GTB kan ti a fi oruko bo ni asiri (tori aabo) ni ilu Eko , ti o si na ika owo re maraarun...
OMO AKIN .......Yoruba lo so pe " Omo Ajanaku kii yara
›
Omo ti Ekun ba bi Ekun ni yo jo" asamo yi lo di'fa fun Ogagun Adeboye Obasanjo omo Yoruba atata ti o tun je Omo bibi inu Aare ...
Monday, September 8, 2014
Ori To Kẹ: Yoruba bọ, wọn ni ‘Oun gbogbo lọwọ ori
›
Edumare tun wa fi awọn nka mere-mere se ‘ẹsọ ori’ Bi oju, ahọn, eti, eyin ati ọpọlọ Oju ni fitila ara, ahọn ni ọrọ, ọrọ nii yọ obi lápò...
‹
›
Home
View web version