Ọmọ Oódua - Art & Culture
Yoruba Art And Culture
Pages
(Move to ...)
News
About Us
Entertainment
Naija Gist
Art
Disclaimer
Privacy Policy
▼
Saturday, August 30, 2014
MICHELLE AYA OBAMA.
›
Michelle iyawo Aare Orile ede America ni e n wo yi , Omo eniyan dudu ni oun ati oko re , itan so pe nigba ti o wa nile iwe girama awon om...
Tuesday, August 26, 2014
EEMO WOLU O: Awon ti'o gbero ati pa awa omo Nigeria
›
. Awon eniyan wo lo wa nidi pe won gbero ati pa awa omo Nigeria run na , Haba kin lo de. Oro yi lo n jade lenu awon omo Orile ede yi lor...
Monday, August 25, 2014
NNKAN N BE O: Oyun osu meje ni inu omo odun mejila.
›
. Oro Olorun ko ni lo lai se , orisirisi la n ri , bee ni orisirisi la n gbo. Bi o tile je pe bi a ba n wi awon Thomas alaigbagbo kan a ...
Saturday, August 23, 2014
O MA SE O! Chibok ti awon Boko Haram ji ko
›
Haaaa , abiyamo , e ku oro omo , bi eniyan ba je ori ahun ti o ba de ibi ti awon obi awon omo ile iwe Chibok ti awon Boko Haram ji ko n...
16 comments:
Thursday, August 21, 2014
Ẹyin ara wa tootọ, Ẹ jọwọ, ẹ ba wa da sí eto aṣalẹ t'ení.
›
Ibeere tení ní: "Darukọ awọn oríṣíríṣí Ila tí a ma nkọ n'ílẹ Yorùbá" Ẹyín ọjọgbọn, ẹ ba wa da sí
Wednesday, August 20, 2014
Oniroyin omo ile America
›
A gbo so igba nu ni iroyin ti oniroyin omo ile America kan ti awon Musulumi kan mu ni igbekun lati 2012 sugbon ti won du l'orun lana. ...
Tuesday, August 19, 2014
Owo Te Odaran Ni Ilu Eko
›
Owo awon agbofinro ti won n so papa oko Ofurufu Muritala ni ilu Eko ti te afurasi odaran kan ti won ni o jewo pe won ni ki oun ati awon ...
‹
›
Home
View web version