Ọmọ Oódua - Art & Culture
Yoruba Art And Culture
Pages
(Move to ...)
News
About Us
Entertainment
Naija Gist
Art
Disclaimer
Privacy Policy
▼
Thursday, July 31, 2014
KABIYESI OLORUN: Ibrahim pade omobinrin arewa kan ti oruko re n je Ameena
›
. Ase otito ni oro awon agba ti won so pe "Olodumare ko gbagbe enikankan"be e gege ni oro Arif Ibrahim Tambe eni ti ko ga ju ese...
Wednesday, July 30, 2014
O MA SE O !!! El-Rufai padanu okan ninu awon omokunrin re
›
Oro yi lo n jade lenu awon ti won sun mon eni ti o ti fi igba kan je Minista Abuja tele , Malam Nasir El-Rufai eni ti o padanu okan ninu ...
Monday, July 28, 2014
KIN LO DE ? Isele Ni deedee agogo meji osan
›
Ni deedee agogo meji osan yi ni Obinrin kan sa deedee yo sibi ti awon olopa ti n seeto lati ko awon oku ti bombu pa laaro yi kuro nile ni...
Sunday, July 27, 2014
KIN LO DE ? Ibeere yi ni awon olugbe ipinle Osun n beere lowo ara won
›
Ni pataki awon olugbe ilu Ilesa nibi ti awon ololufe egbe APC ati PDP ti fija peeta lori ibo ti n bo lona , ti eniyan meji si gbemi min t...
Friday, July 25, 2014
Lo ba tan, OWO TE OSIKA EDA !!!
›
Owo ma ti te e o , ni aye ijohun ni a maa n so pe awon obinrin ni oju aanu sugbon bayi,Opolopo won ni won daju ju ile agba lo. Ti e ko ...
Ẹ jọwọ, ẹ ba wa da sí eto aṣalẹ t'ení.
›
Ẹyin ara wa tootọ, Ẹ jọwọ, ẹ ba wa da sí eto aṣalẹ t'ení. Ibeere tení ní: "ṣe o ba aṣa Yoruba mu kí obínrín kọ ẹnu ífẹ...
Tuesday, July 22, 2014
Igbeyawo ara oto ti o sele ni Orile Ede
›
Huuummm, bi aye ba n lo si opin orisirisi nkan ti ko sele ri ni yoo ma waye , iru re ni eyi ti o sele ni Orile Ede South Africa laipe ...
‹
›
Home
View web version