Ọmọ Oódua - Art & Culture
Yoruba Art And Culture
Pages
(Move to ...)
News
About Us
Entertainment
Naija Gist
Art
Disclaimer
Privacy Policy
▼
Wednesday, June 25, 2014
Opuro Orebirin f'iku Se Ifa Je
›
Leyin opolopo ojo ti won ti n wa eni ti o pa arabinrin Cicely Bolden , eni odun mejidinlogbon (28), oko afesona re ma ti jade si gbangba...
Tuesday, June 24, 2014
OSIKA EDA. Owo ti te e o
›
Owo ti te e o , ani owo ma ti te e,owo ti te osika eda yen ti o pa omo bibi inu ara re nitori iresi (rice) agolo kan pere.Kingsley Ekerete...
Sunday, June 15, 2014
KINI KI A PE EYI O !!! Se efun ni ki a pe e ni tabi eedi
›
Sa deede ni awon kokoro oyin igan (bees) bi egberun lona ogun (20,000) bo arabinrin ti o n koja niwaju ile itaja nla kan ni opopona Victo...
OWO TI TE WON O !!! Owo te Meta ninu awon omo iko gbemi gbemi Boko Haram ni ojo eti
›
Meta ninu awon omo iko gbemi gbemi Boko Haram ti won pa opolopo eniyan laipe yi ni Ijoba Ibile Gwoza ni iko JTF ti te ni ijeta ojo et...
Sunday, June 1, 2014
Ohun Buruku Ni Ko Taka Sori
›
Nibi ti omo Yoruba bawa, tI aba ri eni so oro buruku tabi oro odi, awon omo Yoruba ti oba wa ni be ma taka l'emeta ni kiakia, won a t...
Friday, May 23, 2014
O MA SE OOO: kin lo fa iku arabinrin Mary Paul ?
›
O MA SE OOO:- Ti eniyan ba je ori ahun ti o ba de Chibock l'oni yo sunkunn , nibi ti awon ara adugbo naa ti n ba idile alagba Paul ...
NNKAN N BE. Ni ojo'ru ose yi ni isele nla kan sele ni agbegbe Ajegunle ni ilu Eko
›
Gege bi ogbeni Okafor ti isele naa soju re se so,o ni sadeede ni eye kan sadeede ja lule lati oju ofurufu,ka to fo ka to wi eye naa ti y...
‹
›
Home
View web version