Ọmọ Oódua - Art & Culture
Yoruba Art And Culture
Pages
(Move to ...)
News
About Us
Entertainment
Naija Gist
Art
Disclaimer
Privacy Policy
▼
Friday, May 23, 2014
O MA SE OOO: kin lo fa iku arabinrin Mary Paul ?
›
O MA SE OOO:- Ti eniyan ba je ori ahun ti o ba de Chibock l'oni yo sunkunn , nibi ti awon ara adugbo naa ti n ba idile alagba Paul ...
NNKAN N BE. Ni ojo'ru ose yi ni isele nla kan sele ni agbegbe Ajegunle ni ilu Eko
›
Gege bi ogbeni Okafor ti isele naa soju re se so,o ni sadeede ni eye kan sadeede ja lule lati oju ofurufu,ka to fo ka to wi eye naa ti y...
Thursday, May 22, 2014
OKUNRIN TO SO ARA RE DI OBINRIN TI DARA SI O
›
Nigba ti a gbe iroyin yi ni bi osu mefa seyin opo eniyan ni won pe wa ni opuro nigba naa,bi o tile je pe o soro lati gbabo looto sibe oti...
Wednesday, May 21, 2014
Aja to R'ele Ekun To bo
›
Aja to r'ele Ekun to bo , ka ki I ku ewu ni o , bee ni oro Omobinrin yi Godiya Simon eni ti o wa lara awon omo ile iwe Chibok ti aw...
Tuesday, May 20, 2014
KIM K ATI KANYE WEST FE SE IGBEYAWO
›
Gege bi iroyin to n te wa lowo bayi ni pe,Omobinrin ti o maa n fi Oyan ati idi re ya foto fun awon ile ise ti won ba fe irufe aworan bee m...
Monday, May 19, 2014
T'ORI OLORUN: Adajo kan ni Orile Ede Sudan ni ki won lo yegi fun abileko kan titi emi yo fi bo ni ara re
›
N se ni igbe ekun n ta l'otun ati l'osi ni ojo'bo ose ti o koja nigba ti adajo kan ni Orile Ede Sudan ni ki won lo yegi fu...
Sunday, May 18, 2014
Eemo W'olu ooo: ni ilu Ilobu ni ijoba ibile Irepodun ni Ipinle Osun
›
Laaro ojo'bo ninu ose ti o koja ti awon ara ilu Ilobu ni ijoba ibile Irepodun ni Ipinle Osun ji,n se ni gbogbo olugbe ilu naa n ko h...
‹
›
Home
View web version