Ọmọ Oódua - Art & Culture
Yoruba Art And Culture
Pages
(Move to ...)
News
About Us
Entertainment
Naija Gist
Art
Disclaimer
Privacy Policy
▼
Wednesday, April 30, 2014
Ori To Kẹ Yoruba bọ, wọn ni ‘Oun gbogbo lọwọ ori ni’.
›
Edumare tun wa fi awọn nka mere-mere se ‘ẹsọ ori’ Bi oju, ahọn, eti, eyin ati ọpọlọ Oju ni fitila ara, ahọn ni ọrọ, ọrọ nii yọ obi lápò...
Monday, April 28, 2014
EJA N'BAKAN: Itan Eja Ni Abi Akan
›
AKAN ati EJA je pataki ninu awon opolopo omo Yeyemoja Olokun. Ni ojo kan ni Yeyemoja pe omo re EJA-(fish) pe ki o lo ba ohun sin gbese. Ni...
3 comments:
Saturday, April 26, 2014
Ekú déédé ìwòyí o! - Ìbéèrè mi nì
›
Ekú déédé ìwòyí o! Èyin èèyàn mi lórí ètò yí, ejòwó ebámi dásí òrò yí, bí àwon baba wa nílè yorùbá báfé júbà won a máa so báyìí pé; ÌBÀ ...
Thursday, April 24, 2014
ERIN WO. Erin wo, Ajanaku sun bi oke.
›
Eyin ka ile erin ti wo , Afemojo ku enu isa n s'ofo............................. Lana ojo ketalelogun , osu Kerin ni iku wole to mu...
ASIRI TU: ni adugbo Aperin ni ilu lbadan
›
Laipe yi ni owo te obinrin kan ni adugbo Aperin ni ilu lbadan , nigba ti owo awon Olopa ti o n dagbo mo awon ti won n fi omo s'owo ...
NNKAN N BE. Ireti obi ni pe ki obi jere omo l'ojo ale
›
Ireti obi ni pe ki obi jere omo l'ojo ale.Sugbon ni ti Elizabeth ko ma ri bee o, Looto,o lo s'ile iwe alakobere,o lo si girama l...
Sunday, April 20, 2014
EBI OOOO !! awon Boko Haram
›
!!! Ninu ose ti a wa yi ni awon Boko Haram se saka ni ibudoko kan ti o gbajumo ni ilu Abuja ti ogunlogo emi si sonu sinu ikolu naa bakan n...
‹
›
Home
View web version